For faster navigation, this Iframe is preloading the Wikiwand page for Eyín.

Eyín

A chimpanzee displaying its teeth

Eyín jẹ́ ẹ̀yà ara kan tí ó le koko tí kìí rọ̀ tí ó ma ń hù jáde láti inú erìgì nínú ẹnu tí a ń lò láti jẹun tàbí fọ́ egungun. Gbogbo ẹranko tí ó ní egungun lẹ́yìn tí wọ́n sì ma ń rún oúnjẹ lẹ́nu ni wọ́n ma ní eyín. Nígbà tí pupọ̀ nínú wọn ma ń fi eyín ṣọdẹ tàbí dáàbò bo ara wọn lọwọ́ ewu. Àwọn onímọ̀ fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé eyín kìí ṣe egungun rárá bí ó ti wulẹ̀ kí ó mọ, amọ́ eyín jẹ́ àkójọ pọ̀ àwọn tíṣù kan tí wọ́n ń pè ní ectoderm ni wọ́n para pọ̀ di eyín.

Ìrísí eyín ni ara gbogbo eranko elegungun ma n jọra wọn, bi o tileẹ̀ jẹ́ wípé ìyàtọ̀ ma n wà níbi títòjọ wọn. Eyín gbogbo àwọn ẹranko elégungun sábà ma ń fẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin. Bákan náà ni ó ma ń rí lára àwọn ẹja àti àwọn ọ̀ọ̀nì. Àmọ́ lára àwọn ẹja kan tí wọ́n ń pè ní teleost ita egungun enu won ni eyin won ma n hu si, lara awon alangba inu apa kan ori egungun enu won ni eyin won ma wa.

Lara awon eja oni kerekere bi eja saaki, eyin won sopo mo ligaments ti o nipon to si sopo mo kerekere arungbon won. [1]

Híhù eyín láàrín àwọn ẹranko

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Híhù eyín láàrín àwọn ẹranko elégungun ma ń sábà jẹ́ bá ká ń náà, àmọ́ ìyàtọ̀ ma ń wà láàrín ipò àti bí wọ́n ṣe ń hù láàrín ẹranko sí ẹranko. Kìí ṣe àwọn ẹranko nikan ni ó ma ń hu eyín, àwọn ẹja àti ẹran inú omi náà ma ń hu eyín.[2][3][4] Eyín kìí sábà hu nínú ẹnu nikan gẹ́gẹ́ bí àwọn ẹ́yà ẹranko kan ṣe ma hu ti wọn. Híhù eyín láàrín àwọn ẹja sábà ma ń wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ ẹnu wọn, nígbà tí ti àwọn kan so mọ́ ẹ̀gbẹ́ erìgì wọn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [5][6]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Romer, Alfred Sherwood; Parsons, Thomas S. (1977). The Vertebrate Body. Philadelphia, PA: Holt-Saunders International. pp. 300–310. ISBN 978-0-03-910284-5. 
  2. Romer, Alfred Sherwood; Parsons, Thomas S. (1977). The Vertebrate Body. Philadelphia, PA: Holt-Saunders International. pp. 300–310. ISBN 978-0-03-910284-5. 
  3. "Root or crown: a developmental choice orchestrated by the differential regulation of the epithelial stem cell niche in the tooth of two rodent species". Development 130 (6): 1049–57. March 2003. doi:10.1242/dev.00332. PMID 12571097. 
  4. Hunt AM (1959). "A description of the molar teeth and investing tissues of normal guinea pigs". J. Dent. Res. 38 (2): 216–31. doi:10.1177/00220345590380020301. PMID 13641521. https://www.semanticscholar.org/paper/8015c2356eeef37b14df1c69d4cfd9c932187970. 
  5. McCOLLUM, MELANIE; SHARPE, PAUL T. (July 2001). "Evolution and development of teeth". Journal of Anatomy 199 (1–2): 153–159. doi:10.1046/j.1469-7580.2001.19910153.x. PMC 1594990. PMID 11523817. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=1594990. 
  6. nature.com, Fossil scans reveal origins of teeth, 16 October 2013
{{bottomLinkPreText}} {{bottomLinkText}}
Eyín
Listen to this article

This browser is not supported by Wikiwand :(
Wikiwand requires a browser with modern capabilities in order to provide you with the best reading experience.
Please download and use one of the following browsers:

This article was just edited, click to reload
This article has been deleted on Wikipedia (Why?)

Back to homepage

Please click Add in the dialog above
Please click Allow in the top-left corner,
then click Install Now in the dialog
Please click Open in the download dialog,
then click Install
Please click the "Downloads" icon in the Safari toolbar, open the first download in the list,
then click Install
{{::$root.activation.text}}

Install Wikiwand

Install on Chrome Install on Firefox
Don't forget to rate us

Tell your friends about Wikiwand!

Gmail Facebook Twitter Link

Enjoying Wikiwand?

Tell your friends and spread the love:
Share on Gmail Share on Facebook Share on Twitter Share on Buffer

Our magic isn't perfect

You can help our automatic cover photo selection by reporting an unsuitable photo.

This photo is visually disturbing This photo is not a good choice

Thank you for helping!


Your input will affect cover photo selection, along with input from other users.

X

Get ready for Wikiwand 2.0 🎉! the new version arrives on September 1st! Don't want to wait?