For faster navigation, this Iframe is preloading the Wikiwand page for Ọjà.

Ọjà

Ọjà jẹ́ àwùjọ kékeré tàbí ńlá tí ètò kárà-kátà tàbí ìdókowò pọ̀ láàrín olùtajà àti olùrajà ti ma ń wáyé, yàlà ní àrín ìlú ni tàbí lẹ́yìn odi.[1]

Oríṣi Ọjà tó wà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní aye àtijọ́, ọjà pin sí oríṣi méjì.

  1. Ọjà ìlú
  2. Ọjà oko

Ọjà ìlú tàbí Ọjà Ọba

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

ni ibi tí Kárà-kàtá lórí oríṣiríṣi lórí ohun kóhun tí ènìyàn bá fẹ́ ra ti ń wáyé nípa lílé ọjà síléẹ̀ fún títà. Látorí gbogbo ohun tí ẹnu ń jẹ bi ata ẹ̀fọ́ gàrí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ohun tí ara ń wọ̀ bí bàtà, fìlà, aṣọ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Irúfẹ́ ọjà yí ma ń sábà wà ní iwájú Afin Ọba.[2]

Èyí ni ọjà tí ó dá lórí ohun Ire oko lásán. Irè oko yí lè jẹ́ ẹ̀fọ́, ata, iṣu àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ọjà wọ̀nyí ni wọ́n ma ń kò wà láti ta ní inú ọjà àárín ìlú.

Èyí jẹ́ ọjà tí wọ́n ma ń ra lá orí ẹ̀rọ aye-lu-jára láti inú ilé ẹni. Ẹ̀wẹ̀, wọ́n tún ma ń kọ́ àwọn àgbàọ́ kan lọ́nà ará ọ́tọ̀ tí wọn yóò sì pàtẹ ọjà tí wọ́n fẹ́ ta síbẹ̀, àwọn ọjà wọ̀nyí ma ń yàtọ̀ sí Irúfẹ́ ọjà tí a lè bá pàdé ní ọjà ìlú tàbí ọjà Ọba, nítorí àwọn ọjà tí oo bá pàdé níbeẹ̀ kii ṣe ọjà àtoko wà, bí kìí ṣe àwọn ọjà inú ọ̀rá (nylon) tàbí ọjà inú Ike tí wọn kii lé sílẹ̀ lásán.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "What is Markets? Definition of Markets, Markets Meaning". The Economic Times. Retrieved 2020-01-30. 
  2. "Market - economics". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2020-01-30. 
{{bottomLinkPreText}} {{bottomLinkText}}
Ọjà
Listen to this article

This browser is not supported by Wikiwand :(
Wikiwand requires a browser with modern capabilities in order to provide you with the best reading experience.
Please download and use one of the following browsers:

This article was just edited, click to reload
This article has been deleted on Wikipedia (Why?)

Back to homepage

Please click Add in the dialog above
Please click Allow in the top-left corner,
then click Install Now in the dialog
Please click Open in the download dialog,
then click Install
Please click the "Downloads" icon in the Safari toolbar, open the first download in the list,
then click Install
{{::$root.activation.text}}

Install Wikiwand

Install on Chrome Install on Firefox
Don't forget to rate us

Tell your friends about Wikiwand!

Gmail Facebook Twitter Link

Enjoying Wikiwand?

Tell your friends and spread the love:
Share on Gmail Share on Facebook Share on Twitter Share on Buffer

Our magic isn't perfect

You can help our automatic cover photo selection by reporting an unsuitable photo.

This photo is visually disturbing This photo is not a good choice

Thank you for helping!


Your input will affect cover photo selection, along with input from other users.

X

Get ready for Wikiwand 2.0 🎉! the new version arrives on September 1st! Don't want to wait?