Àdájọba
Ìkan nínù àwọn àyọkà Ìṣèlú lórí |
Ìṣetọlọ́ba |
---|
Absolute · Constitutional
Elective · Non-Sovereign · Regency |
|
Magna Carta
Foundation of the Ottoman Empire Glorious Revolution French Revolution First Spanish Civil War First French Empire Second French Empire Fall of Qing Dynasty Russian Revolution of 1917 Siamese Revolution of 1932 Second Spanish Civil War Birth of the Italian Republic Iranian Revolution Modern Cambodia Nepalese Civil War |
|
Politics portal |
Àdájọba tabi Ìdọ́bajẹ (monarchy) je iru ijoba kan nibi ti gbogbo agbara oloselu wa patapata tabi ni oloruko lowo enikan tabi awon eyan kan. Gege bi ohun oloselu, oludajoba ni olori orile-ede, won wa nipo yi titi di igba ti wo ba ku tabi sakuro lori ite, be sini "o je yiyasoto kuro lodo gbogbo awon omo egbe orile-ede miran."[1] Eni toun solori ijoba adajoba ni aunpe ni adobaje tabi oludajoba. Iru ijoba yi lo wopo laye nigba ijoun ati oju dudu.
Lowolowo, awon orile-ede 44 ni won ni oludajoba gege bi awon olori orile-ede, 16 ninu won je Ile Ajoni ti won gba Queen Elizabeth II gege bi olori orile-ede won.
Ìkan nínú àyọkà Ìṣèlú |
Basic forms of government |
---|
Power structure |
Power source |
|
List of forms of government |
Politics portal |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Bouvier, John, and Francis Rawle. Bouvier's Law Dictionary and Concise Encyclopedia. 1914. 2237-2238.
Text is available under the CC BY-SA 4.0 license; additional terms may apply.
Images, videos and audio are available under their respective licenses.